Oto Laleye – Ola Lyrics

LORD we give you all the glory and the praise
only You alone art worthy Great I AM
LORD we give You all the glory,only You alone art worthy
LORD we give You all the glory and the praise

Ola l’e wo l’aso
Ogo l’aso ileke
Iji l’egun l’esin,
AWAMARIDI OLODUMARE.

Rep: LORD we give you all the glory and the praise

GOD’S  APPRAISAL

King of kings! LORD of lords.
It is said The Heavens declare Your glory and the firmament show His handy works. Who is compared to You
Ogbeja keru o bonija, Olowo gbogboro, Alewilese,Aleselewi. Oba to da monamona fun ojo. Akodaye, Aseda  Orun. Asoro kolu bi ogiri gbigbe. Nana bi owo aso.
He is crowned in glory, crowned in honour…. Atofarati bi oke. Adun barin, Adunbalo. Oni majemu KAAABIESI  RE OLUWA!

Rep:. Ola l’ewo l’aso…..

OLUWA joba jeki awon enian ko wariri! O joko larin awon KERUBU, jeki aye ki o ta gbongbo! OLUWA tobi ni Sioni. O gaju gbogbo orile’de lo. Kasi maa sin nibi Mimo Re….Mimo ni Oun eeee Jagunjagun ode Orun oo BABA oo! Owibe sebe… Adani male gbagbe Alagbara o….
You told the Mountains to form….Out of the mouth of Children You ordained strength.
Oni latetekose ni Oro wa, Oro wa pelu OLORUN, OLORUN si ni Oro na…Olupamo, Oludande, Olugbala!
Mimo Mimo Mimo Mimo OLUWA OLORUN awon Omo Ogun
KABIESI RE OLUWA!!!

 
Get A Professional Artwork Graphic Design Now (Here)

DOWNLOAD: Mr Lile - Mummy Anyi
Loading...
READ ALSO  Calvin Harris - Faking It Lyrics

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*